Template:Anonymous-EU/yo
From OpenMedia
Àwòrán yìí (tàbí fáìlì amohùnmáwòrán míràn) wà ní ìgboro nítorípé ẹ̀tóàwòkọ rẹ̀ ti parí àti pé olùdá rẹ̀ jẹ́ aláìlórúkọ. Èyí kan Ìṣọ̀kan Europe àti àwọn orílẹ̀-èdè pẹ̀lú ẹ̀tọ́àwòkọ ìgbà ọdún 70 lẹ́yìn tí iṣẹ́ náà jẹ́ ti ará ìgboro àti tí olùdá kò fi ara wọn hàn. |
||
|
Àkíyèsí: Ní Jẹ́mánì, ó sì ṣe é ṣe ní àwọn orílẹ̀-èdè míràn, àwọn iṣẹ́ aláìlórúkọ pàtó kan tí wọ́n tẹ̀jáde síwájú ọjọ́ 1 Ọṣù Keje, 1995 ní ẹ̀tọ́àwòkọ títí dé 70 ọdún lẹ́yìn ikú olùdá wọn. Ẹ wo gbólóhùn ọ̀rọ̀ tó parí Aktuelle Rechtslage in Deutschland. Tí olùdá bá fi ara rẹ̀ hàn nígboro, ẹ mọ́ lo àdàkọ yìí. Tí iṣẹ́ náà bá jẹ́ aláìlórúkọ tábí olórúkọèké (f.a., ó jáde lábẹ́ orúkọ ilẹ́-iṣẹ́ kan tàbí àgbájọ), ẹ lọ àdàkọ yìí fún àwọn àwòrán tó jáde ní ọdún 70 sẹ́yìn tàbí jùbẹ́ẹ̀ lọ.
Fún iṣẹ́ tó jẹ́ ti ìgboro ní orílẹ̀-èdè Ilẹ̀ọba Aṣọ̀kan, ẹ jọ̀wọ́ ẹ wòó bóyá ẹ le lo Template:PD-UK-unknown dípò.
|
ÀKÍYÈSÍ: Ẹ jọ̀wọ́ ẹ má lo àdàkọ yìí tàràrà! Ó wà lásán fún ìyédèpadà. Ẹ lo {{Anonymous-EU}} dípò rẹ̀!
NOTE: Please do not use this template directly! This is just for translation. Use {{Anonymous-EU}} instead!